She continually gives me;
 My robe
put on my crown; 
Because, he knows; 
I have immortal longings;
 In
me-endless love!
Eniola mi dara lomo!
Ibadi aran dara lomo!
Toluwalope dara lomo!
Omo Olarotimi dara lomo!
Omo pupa yi dara lomo!
O pon lati ori desale:
Eniola Gold dara lomo;
Omo Arigidi dara lomo;
Kini maa ri fun o?
Maa korin ife didun fun;
Eniola’s a pretty gal pretty gal;
Eniola’s a pretty gal pretty gal;
She is my angel!
==DEOLA





No comments:
Post a Comment