Translate

DEOLA

DEOLA

Thursday, December 15, 2011

RE: PETROL SUBSIDY

 
KINI MO KO SOKE YI O?
‘S’ LO NJE;
‘S’ LO NJE;
KINI MO KO SOKE YI O?
‘U’ LO NJE;
‘U’ LO NJE;
KINI MO KO SOKE YI O?
‘B’ LO NJE;
‘B’ LO NJE;
KINI MO KO SOKE YI O?
‘S’ LO NJE;
‘S’ LO NJE;
KINI MO KO SOKE YI O?
‘I’ LO NJE;
‘I’ LO NJE;
KINI MO KO SOKE YI O?
‘D’ LO NJE;
‘D’ LO NJE;
KINI MO WA KO SOKE YI O?
‘Y’ LO NJE;
‘Y’ LO NJE;
E BAMI FESO GBE;
SUB-SI-DY! SUB-SI-DY!
ODUN NEW YEAR NIGERIANS!
KI OLRUN KO SO WA DELE O.
ENI TO FI JONA SERE;
KELE AGBE!
NITORI, KI LE NFI JONA PE?
PRESIDO OBA ALASE OBA;
IJAW DUDU BI ARO!
PRESIDO OBA ALASE OBA;
KI LE NFI JONA PE?
PRESIDO OBA ALASE OBA. ====deola mcaguns.1 comment:

 1. DUGBE DUGBE DUGBE SUBSIDY YI;
  WAHALA TIO FA SILE , KO NISE KO;
  AMO SA, AWON KAN WA NI KAMPE;
  E SURE? GBOGBO WON YIO SI GBA
  PE IJALO TI O LE WO SOKOTO OMIRAN O;
  SUGBON IJALO YIO BO SOKOTO OMIRAN
  KIA-MOSA, WERE-WERE;
  IJALO KO SE FOJU DI, OMIRAN LO SORA;
  OMO NIGERIA KO SE KO LU;
  NITORI, WON TI BOLUWA DURO.

  ReplyDelete

Followers

Contact Form

Name

Email *

Message *