Diezani pa wa;
Gbe wa pon lekan;
Ayaba lo je!
Gbogbo agbara;
Lowo re lo wa;
Carry go;
Tete pa wa;
Gbe wa pon lekan;
Mumu ni wa!
Jonathan pa wa;
Gbe wa pon lekan;
Mumu ni wa!
Go on soun;
Tete pa wa;
Gbe wa pon lekan;
Nitori Ijaw ni e!
You and Diezani;
Gbogbo agbara;
Lowo yin lo wa;
E pa wa;
Gbe wa pon lekan;
Mumu ni wa!
TRANSLATION
Diezani, kill us;
Back us at once;
U’re the king’s
wife;
You’ve gotten;
The whole might;
In your hands;
Tarry not!
Get us killed;
Back us at once;
We are fools!
Jonathan, kill us;
Back us at once;
We are fools!
Hurry up;
Get us killed
Back us at once;
U are Ijaw man!
You and Diezani;
Tarry not!
You’ve gotten;
The whole might;
In your hands;
Get us killed;
Back us at once;
We are rubbish!
=DEOLA
To ba fe lowo lojiji;
ReplyDeleteOne amazing manner;
To ba ti de Nigeria;
Ko bere PDP;
To ba ti de PDP;
Bere Diezani Alison;
In subsidy scam;
Oga ni won je!
Esu biri biri;
Ke bomi o o;
Iwaju lo loko yi;
Nwa wa lo;
Bi ehin ni olok yi;
Nwa wa lo;
Mio mo o!
Mio mo ye o!
Mio mo o!
After 100 years;
Of nationhood;
Okunkun biri-biri;
Lo kari ile!
Esu biri biri;
Ke bomi o o;
Iwaju ni Jonathan;
Nwa wa lo;
Bi ehin ni Jonathan;
Nwa wa lo;
Mio mo o!
Mio mo ye o!
Talo mo o?
Won ni kama su sepo;
Diezani su sepo;
Won o bawi rara!
Orekelewa, ayaba nise!
Won ni e ma to s’ala;
Diezani to s’ala;
Won o bawi rara!
Esu biri biri;
Ke bomi o o;
Iwaju lo loko yi;
Nwa wa lo;
Bi ehin ni olok yi;
Nwa wa lo;
Mio mo o!
Mio mo ye o!
Mio mo o!
The thieves are;
Regrouping lojujumo;
Esu biri biri;
Ke bomi o o;
Iwaju ni Jonathan;
Nwa wa lo;
Bi ehin ni Jonathan;
Nwa wa lo;
Talo mo o!
Mio mo ye o!
Mio mo o!
=DEOLA
[KSA adopted]