Translate

DEOLA

DEOLA

Sunday, February 9, 2014

DARRY KENNYSTIC!!!

Omo koinde mi; 
Ko ni ku lewe;
Wa daagba;
Wa daarugbo;
Dandan ni.
Ejire mi;
Ko ni ku lewe;
Wa daagba;
Wa daarugbo;
Dandan ni.
Omo Daramola;
Ko ni ku lewe;
Wa daagba;
Wa daarugbo;
Dandan ni.
A nbinu ori;
Ka fi fila;
De dodo;
Wa daagba;
Wa daarugbo;
Dandan ni.
Omo koinde mi;
Ko ni ku lewe;
Wa daagba;
Wa daarugbo;
Dandan ni.
Ejire, isokun;
Omo edunjobi;
Wa daagba;
Wa daarugbo;
Dandan ni.
Omo Aromolaran;
Owa Obokun;
Ko ni ku lewe;
Wa daagba;
Wa daarugbo;
Dandan ni!!!
HAPPY BIRTHDAY 2 YA!!!
=DEOLA

No comments:

Post a Comment

Followers

Contact Form

Name

Email *

Message *