Ile Toluwalope;
Chorus:
Eniola!
Pupa yemi;
Chorus:
Ibadi aran o!
Orekelewa;
Chorus:
Omo Zaki o!
Nibo ni ile onitire o, eeh;
Akoko ni ile onitemi o, eeh;
Ile Toluwalope;
Chorus:
Eniola!
Pupa yemi;
Chorus:
Ibadi aran o!
Orekelewa:
Chorus:
Omo Zaki o!
Nibo ni ile onitire o, eeh;
Ondo ni ile onitemi o, eeh;
Ogun laka aye;
Chorus:
Okili ni eran!
Ile Toluwalope;
Chorus:
Eniola!
Pupa yemi;
Chorus:
Ibadi aran o!
Orekelewa:
Chorus:
Omo Zaki o!
(Piano, guitar, drum, percussion,
Interlude in soukuso blues)
=DEOLA